Kuwaiti
Orílẹ̀-èdè Kuwaiti (Lárúbáwá: دولة الكويت, pronounced [dawlat alkuwayt]) je Ile-Emiri Arabu aladani to ni bode mo Saudi Arabia ni guusu ati Irak ni ariwa ati iwoorun. Ijinna to pojulo lati ariwa de guusu je 200 km (120 mi) ati lati ilaoorun de iwoorun je 170 km (120 mi). Iposieniyan re je 2.889 legbegberun ati agbegbe 18,098 km².
State of Kuwait دولة الكويت Dawlat al-Kuwayt |
||||||
---|---|---|---|---|---|---|
|
||||||
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè: Al-Nasheed Al-Watani |
||||||
![]() Ibùdó Kuwait |
||||||
Olúìlú (àti ìlú títóbijùlọ) | Kuwait City 29°22′N 47°58′E | |||||
Èdè àlòṣiṣẹ́ | Arabic | |||||
Orúkọ aráàlú | Ará Kuwait | |||||
Ìjọba | Constitutional hereditary emirate[1] | |||||
- | Emir | Sabah Al-Ahmad Al-Jaber Al-Sabah | ||||
- | Prime Minister | Nasser Mohammed Al-Ahmed Al-Sabah | ||||
Establishement | ||||||
- | First Settlement | 1613 | ||||
- | Bani Utbah tribe foundation | 1705 | ||||
- | Anglo-Ottoman Convention | 1913 | ||||
- | Independence | 19 June 1961 | ||||
Ààlà | ||||||
- | Àpapọ̀ iye ààlà | 18,098 km2 (157th) 6,880 sq mi |
||||
- | Omi (%) | negligible | ||||
Alábùgbé | ||||||
- | Ìdíye 2009 | 2,889,042[2] (137th) | ||||
- | census | 2,889,042 (20.1% are kuwaities ,25.6% are indians,30.0% are bangladesh,12.2% are asian , 12.1% are arabs) | ||||
- | Ìṣúpọ̀ olùgbé | 167.5/km2 (68th) 433.8/sq mi |
||||
GIO (PPP) | ìdíye 2009 | |||||
- | Iye lápapọ̀ | $137.450 billion[3] | ||||
- | Ti ẹnikọ̀ọ̀kan | $38,875[3] (11th) | ||||
GIO (onípípè) | Ìdíye 2009 | |||||
- | Àpapọ̀ iye | $114.878 billion[3] | ||||
- | Ti ẹnikọ̀ọ̀kan | $32,491[3] (17th) | ||||
HDI (2006) | ▼ 0.912 (high) (29th) | |||||
Owóníná | Kuwaiti dinar (KWD ) |
|||||
Àkókò ilẹ̀àmùrè | AST (UTC+3) | |||||
- | Summer (DST) | (not observed) (UTC+3) | ||||
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ | right | |||||
Àmìọ̀rọ̀ Internet | .kw | |||||
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù | 965 |
Itumosi
- Nominal.
- Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12.
- "Kuwait". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.
This article is issued from
Wikipedia.
The text is licensed under Creative
Commons - Attribution - Sharealike.
Additional terms may apply for the media files.